
Artist: Niyola
Track : My Prayer
Album: Single
Category: 9jahits
Country: Nigeria
Eniola Akinbo, known professionally as Niyola, is a Nigerian singer and songwriter. use this link below to download this song from Niyola which she titled My Prayer and also use this link below to stream and download My Prayer by Niyola .
Odun lọ sí òpin oh
Oh Lord Guide me
Lord guide me
Eeeh eh yeah
Ọdún lọ sí òpin oooh
Baba mimo
Fi ìsò rẹ sọ wá
Tí ọmọ tó mọ
Owun tí yọ pá wá lekun ooh
Ní ọdún tún tún
Majeki ó sele sì wá bàbà rere
Àṣẹ yí sá mo dùn oooh
Àdúrà kò gbà ẹ ṣe àmín oooh
Olúwa kò sọ wá
Kò fi owun rere sí kemi
Ṣí kéré, sì ké wá
Ọdún lọ sí òpin oooh
Baba mimo
Fi ìsò rẹ sọ wá
Tí ọmọ tó mọ
Owun tí yọ pá wá lekun ooh
Ní ọdún tún tún yí
Majeki ó sele sì wá bàbà rere
Májẹ ká owó leri sunkún
Májẹ fi aṣọ òfo bora
Ogun ro ju je ro ju mú
Màmá je ki oje tó tèmi
Lafiha pípé ni mo fe
Fi tà mi lore
Je rí ń hàn
Je rí lọ
Baba wa se mi lógo
Dabo Ọlọ’run mi
Dabo
Dabo Ọlọ’run mi
Dabo
Màmá je ki wan fi irẹ temi sá pín lè
Màmá je ki oro mi jà sì òfo ni ọdọ Rẹ Olúwa
Dabo Ọlọ’run mi dabo
Nínú ọdún titun irẹ gbogbo ni kò má tomiwa ooh
Nínú ọdún titun ibi gbogbo kò má yàgò fún wa
Everything I do make God win oooh
In this new year this is my prayer
Ọdún lọ sí òpin oooh
Baba rere
Fi ìsò rẹ sọ wá
Olú ọrùn
Owun tí yọ pá wá lekun ooh
Ní ọdún tún tún yí
Majeki ó sele sì wá bàbà rere
Eeeh eeh eh Eeeh yeah
Oooh oooooh ooh oh oooh oh
Ọdún ọdún yí a yabo
Ọdún ọdún yí a mi rí gidi
Peregede ni a hó yẹ
Peregede ni a hó yẹ
Peregede ni a hó yẹ Eeeh
Peregede ni a hó yẹ Eeeh eh
Odun ọdún
Ọdún yí ooh
A mi rí gidi
Peregede ni a hó yẹ
Àmín (this is my prayer)
Àmín (say Amen)
Àdúrà mo gbà Ẹ ṣe àmín oooh
Àmín… Ase
Àmín… E se àmín oooh
You May Also Like
Originally posted on October 4, 2021 @ 9:19 pm
Leave a Reply