Seriki Ft. Obesere – Owo Dollar

Seriki

Artists: Seriki

Featured Artists: Obesere

Title: Owo Dollar

Released: 2020

Category: 9jahits

Country: Nigerian

Seriki is a Nigerian versatile musician, singer, rapper and songwriter  from Ogun State. Use this link below to Download this track from Seriki which is title Obesere and also use this link below to Stream and Download Obesere by Seriki .

 

 

Download Mp3 Here

 

Lyrics of Obesere by Seriki

 

By fire by force we must shine (Seriki)
Obesere ati seriki lowa ninu ogba yii
Won leni Kan n gbemu
Ta lon gbemu?
She e mo bi won she n nawo ni?
Owo dollar lo n na (Lo n na)
Aso dollar lo n wo (Lo n wo)
Ounje dollar lo n je
At the same time (Igbe dollar lo n ya)
Owo dollar lo n na (Lo n na)
Aso dollar lo n wo (Lo n wo)
Ounje dollar lo n je
At the same time (Igbe dollar lo n ya)
Seriki omo owo (O n ya dollar)
IBD dende ( O n ya dollar)
Hushpuppi ( O n ya dollar)
Deji Tinubu ( O n ya dollar)
M.C oluomo ( O n ya dollar)
Niyass ( O n ya dollar)
Wale bouncer ( O n ya dollar)
Alhaji Abass Akande ( O n ya dollar)
See bami pe dolapo ko maa bo
Ko WA gbo nkan ti mo babo
To ba de ti n bo ko pelabo
Tori laleyi o maa konsolijapo
O sha ti ri, awon ti mo ba to
Omo pe Bentley on she egbe Prado
Fine girl obrigado
Ma lo bawon gbenu si kolorado
Bi mo she n bosu mo ma n wonder
Ma wule laagun jina ma bother
Wo nkan to ba fe je ni ko order
Omo gbagbe pe eeyan kan ti lo ti border
Eni eji eta nkan te she se mo pe koda
E fun mi lorobo e mu lepa
Orobo ke agbara mi o ka
Owo dollar lo n na (Lo n na)
Aso dollar lo n wo (Lo n wo)
Ounje dollar lo n je
At the same time (Igbe dollar lo n ya)
Owo dollar lo n na (Lo n na)
Aso dollar lo n wo (Lo n wo)
Ounje dollar lo n je
At the same time (Igbe dollar lo n ya)
Wale Alagbon (O n ya dollar)
Godfather ( O n ya dollar)
Aremo Oniru ( O n ya dollar)
Baddy Osha ( n ya dollar)
Abu Abel ( O n ya dollar)
Dammy Richie ( O n ya dollar)
Oba Bombay( O n ya dollar)
Alhaji Abass Akande ( O n ya dollar)
Owo mo wa na mi o wa ya photo
Mi o wa ya photo
Seriki o wale o de yoo jo
O ni wale o de ni yoo jo
See aa ni payan owo la maa pa
Yee maa wo bi omoge she yapa
Won wo bikini o, tun wo kaba
E ma pa baba oni baba
A n soro hard currency
Make I dey eat your work honestly
E gbegbe ti gbegbe
Gbe sumo mi kin fowo kan bebe
Fine girl unanugo
Owo wa n le ma lo dami duro
Coronavirus o kin pamugbo
Ma lo deru kinni nla barugbo
Owo dollar lo n na (Lo n na)
Aso dollar lo n wo (Lo n wo)
Ounje dollar lo n je
At the same time (Igbe dollar lo n ya)
Owo dollar lo n na (Lo n na)
Aso dollar lo n wo (Lo n wo)
Ounje dollar lo n je
At the same time (Igbe dollar lo n ya)
Baakole (O n ya dollar)
Hundred percent ( O n ya dollar)
Obafemi martins ( O n ya dollar)
Tejumola Jerry ( O n ya dollar)
Idris perpay ( O n ya dollar)
Ade Benz ( O n ya dollar)
Kolawole edun ( O n ya dollar)
Alhaji Abass Akande ( O n ya dollar)
O n ya dollar
O n ya dollar
O n ya dollar
O n ya dollar
O n ya dollar
O n ya dollar
O n ya dollar
O n ya dollar

My name is Sunday oguche Sylvester ... the founder of slyhits.com and you can also call us on our hotline 09052301689

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*