SlyHits.com

HOME | GOSPEL | AMERICAN | NIGERIAN | NEWS | HIGHLIFE | REGGAE



Tope Alabi – Mimo l, oluwa

Posted by: || Categories: Gospel

Advert link

Tope Alabi, also known as Ore ti o common, and as Agbo Jesu is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress.

Use this Download link below to get this song from Tope Alabi which she titled: Mimo l, oluwa

Stream In and Download this track by Tope Alabi which she titled: Mimo l, oluwa

Lyrics of  Mimo l, oluwa by Tope Alabi

Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon Orun mi ke
Mimo
Egbageje irawo
Mimo
Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon Orun mi ke
Mimo
Agbagba merinlelogun
Lorigun mererin aye o
Mimo
Atoke atile
Mimo
Se ni won nke tantan o
Mimo
Ta ni yo gori Oke oluwa
Mimo
Tabi tani yo duro nine
Mimo
Eni to ni owo Mimo, ati aya funfun
Mimo o loluwa
Mimo o Mimo o Mimo o
Mimo o fun fun nene ni
Mimo
Kabiyesi eledumare Oba Mimo
Oba NLA
Gbogbo aye e teriba fun Oba adari hurun
Oba to ni emi inu eniyan pata
Onikokoro aye lowo
Adagagodo emi gbogbo eniyan
Olukangun orun, ajosun edumare
Jigbinigbin, awuwo bi ate ileke
Mimo
Opa tirin kanle o kan orun
Ajosun edumare, minimini ojo to njara o deyan
Mimo
Orun wawa nigba to padabo sipo
Olorun to sosupa dale torutoru
Oba toun Soun gbogbo lasiko lasiko
Oba to let feyin…
https://slyhits.com/wp-content/uploads/2021/04/Tope-Alabi-Mimo-l-oluwa.mp3
Download Mp3 Here


0 Comments

LEAVE A COMMENT

Type Name Below

Type Comment Below

« | »