Tope Alabi – Olorun ni yio ma je + Lyrics

Tope Alabi, also known as Ore ti o common, and as Agbo Jesu is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress.

Use this Download link below to get this song from Tope Alabi which she titled: Olorun ni yio ma je

Stream In and Download this track by Tope Alabi which she titled: Olorun ni yio ma je

Lyrics of Olorun ni yio ma je by Tope Alabi

Olorun ni yio maje
Olorun ni yio maje
Lano loni lola o
Titi de aye raye
Olorun ni yio maje
Olorun ni yio maje
Olorun ni yio maje
Lano loni lola o
Titi de aye raye
Olorun ni yio maje
Alagbara ni kose segun o
Ipa nla kode le ku o
Ayileyipada toni aye ni ikawo
Emi se iba oluda orun o
Emi se iba oluda orun
Olorun ni yio maje
Akoko nda olu da aye
Olorun ni yio maje
Pata pata pira ogo nibi to pari si
Lano loni lola o
Titi de aye raye
Olorun ni yio maje
Ayile tun wa oti wa koto da orun
Tele ri ni ati titi lo ni
Eni nigba ti koni ibere beni ko lopin
Mo juba akoda aye o
Pata pata ogo
Olorun ni yio maje
Eni l’ade to ti d’ade kato da aye
Olorun ni yio maje
Eni l’ade to ti d’ade kato da orun
Lano loni lola o
Titi de aye raye
Olorun ni yio maje
Kosi eni to da nigba to tin joba o
A o to owo eda kan mu ade ori e
Akobi orun o olusaju aye de
Jehovah emi se iba
Ogangan oju awon agbagba merin
Olorun ni yio maje
Iriju oju awon angeli ojojumo
Olorun ni yio maje
Iba eni tawon torun se ti won o dake
Kosi ari yan jiyan lorigun merin orun ati aye
Koni se ayi je olorun mo
Olorun ni yio maje
Iwo nikan ni oma je olorun
Olorun ni yio maje
Oti da lorun koto da orun rara
Kosi ari yan jiyan lorigun merin orun ati aye
Koni se ayi je olorun mo
Olorun ni yio maje
Emi se iba koto kan oro ashiri aye
Olorun ni yio maje
Ashiri aye pelu orun owo re lowa
Lano loni lola o
Titi de aye raye
Olorun ni yio maje
https://youtu.be/Tjnunlxn9BY
https://slyhits.com/wp-content/uploads/2021/04/Tope-Alabi-Olorun-ni-yio-ma-je.mp3

My name is Sunday oguche Sylvester ... the founder of slyhits.com and you can also call us on our hotline 09052301689

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*